Mak 12:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn oluṣọgba wọnni wi fun ara wọn pe, Eyiyi li arole; ẹ wá, ẹ jẹ ki a pa a, ogún rẹ̀ yio si jẹ tiwa.

Mak 12

Mak 12:1-10