Mak 12:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ekeji si dabi rẹ̀, Fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ. Ko si si ofin miran, ti o tobi jù wọnyi lọ.

Mak 12

Mak 12:27-37