Mak 11:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnikẹni ba si wi fun nyin pe, Ẽṣe ti ẹnyin fi nṣe eyi? ẹ wipe, Oluwa ni fi ṣe; lojukanna yio si rán a wá sihinyi.

Mak 11

Mak 11:1-7