Mak 10:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si gbé awọn ọmọ-ọwọ tọ̀ ọ wá, ki o le fi ọwọ́ tọ́ wọn: awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si ba awọn ti o gbé wọn wá wi.

Mak 10

Mak 10:4-16