Mak 1:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si nwasu, wipe, Ẹnikan ti o pọ̀ju mi lọ mbọ̀ lẹhin mi, okùn bata ẹsẹ ẹniti emi ko to bẹ̀rẹ tú:

Mak 1

Mak 1:1-8