Luk 9:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si pè awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ mejila jọ, o si fun wọn li agbara on aṣẹ lori awọn ẹmi èṣu gbogbo, ati lati wò arùn sàn.

Luk 9

Luk 9:1-11