Luk 8:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori o ni ọmọbinrin kanṣoṣo, ọmọ ìwọn ọdún mejila, o nkú lọ. Bi o si ti nlọ awọn enia nhá a li àye.

Luk 8

Luk 8:41-52