Luk 7:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia ti o gbọ́ ati awọn agbowode, nwọn da Ọlọrun lare, nitori a ti fi baptismu Johanu baptisi wọn.

Luk 7

Luk 7:20-31