Luk 5:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn si ti mu ọkọ̀ wọn de ilẹ, nwọn fi gbogbo rẹ̀ silẹ, nwọn si tọ̀ ọ lẹhin lọ.

Luk 5

Luk 5:2-19