Luk 5:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati ijọ enia ṣù mọ́ ọ lati gbọ́ ọ̀rọ Ọlọrun, ti o si duro leti adagun Genesareti,

Luk 5

Luk 5:1-5