Luk 4:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn o si wi fun wọn pe, Emi kò le ṣaima wasu ijọba Ọlọrun fun ilu miran pẹlu: nitorina li a sá ṣe rán mi.

Luk 4

Luk 4:38-44