Luk 4:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati adẹtẹ̀ pipọ ni mbẹ ni Israeli nigba woli Eliṣa; kò si si ọkan ninu wọn ti a wẹnumọ́, bikoṣe Naamani ara Siria.

Luk 4

Luk 4:17-33