Luk 24:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Bẹ̃li a ti kọwe rẹ̀, pe, ki Kristi ki o jìya, ati ki o si jinde ni ijọ kẹta kuro ninu okú:

Luk 24

Luk 24:44-49