Luk 24:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si bẹ̀rẹ lati Mose ati gbogbo awọn woli wá, o si tumọ̀ nkan fun wọn ninu iwe-mimọ gbogbo nipa ti ara rẹ̀.

Luk 24

Luk 24:20-35