Luk 24:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ni ijọ kini ọ̀sẹ, ni kutukutu owurọ̀, nwọn wá si ibojì, nwọn nmu turari wá ti nwọn ti pèse silẹ, ati awọn miran kan pẹlu wọn.

2. Nwọn si ba a, a ti yi okuta kuro li ẹnu ibojì.

Luk 24