Luk 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

A o si fi nyin hàn lati ọdọ awọn õbi nyin wá, ati awọn arakunrin, ati awọn ibatan, ati awọn ọrẹ́ wá; nwọn o si mu ki a pa ninu nyin.

Luk 21

Luk 21:9-17