Luk 20:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn ti a kà yẹ lati jogún aiye na, ati ajinde kuro ninu okú, nwọn kì igbeyawo, nwọn kì si ifà iyawo fun-ni:

Luk 20

Luk 20:33-44