Luk 20:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn olori alufa ati awọn akọwe nwá ọna ati mu u ni wakati na; ṣugbọn nwọn bẹ̀ru awọn enia: nitoriti nwọn mọ̀ pe, o pa owe yi mọ wọn.

Luk 20

Luk 20:16-28