Luk 2:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Josefu pẹlu si goke lati Nasareti ilu Galili lọ, si ilu Dafidi ni Judea, ti a npè ni Betlehemu; nitoriti iran ati idile Dafidi ni iṣe,

Luk 2

Luk 2:1-13