Luk 19:47 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si nkọ́ni lojojumọ ni tẹmpili. Ṣugbọn awọn olori alufa, ati awọn akọwe, ati awọn olori awọn enia nwá ọ̀na ati pa a run,

Luk 19

Luk 19:45-48