Luk 19:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati o sunmọ Betfage on Betaní li òke ti a npè ni Olifi, o rán awọn meji ninu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀,

Luk 19

Luk 19:24-34