Luk 19:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) JESU si wọ̀ Jeriko lọ, o si nkọja lãrin rẹ̀. Si kiyesi i, ọkunrin kan wà ti a npè ni Sakeu, o si jẹ olori