Luk 18:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo wi fun nyin, yio gbẹsan wọn kánkán. Ṣugbọn nigbati Ọmọ-enia ba de yio ha ri igbagbọ́ li aiye?

Luk 18

Luk 18:1-17