Luk 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

O SI wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, Ko le ṣe ki ohun ikọsẹ̀ má de: ṣugbọn egbé ni fun ẹniti o ti ipasẹ rẹ̀ de.

Luk 17

Luk 17:1-8