Luk 12:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun wọn pe, Kiyesara ki ẹ si mã ṣọra nitori ojukòkoro: nitori igbesi aiye enia ki iduro nipa ọ̀pọ ohun ti o ni.

Luk 12

Luk 12:9-16