Luk 11:53 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ti nwi nkan wọnyi fun wọn, awọn akọwe ati awọn Farisi bẹ̀rẹ si ibinu si i gidigidi, nwọn si nyọ ọ lẹnu lati wi nkan pipọ:

Luk 11

Luk 11:49-54