Luk 11:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li ọkan ninu awọn amofin dahùn, o si wi fun u pe, Olukọni, li eyi ti iwọ nwi nì iwọ ngàn awa pẹlu.

Luk 11

Luk 11:38-54