Luk 11:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oju ni imọlẹ ara: bi oju rẹ ba mọ́, gbogbo ara rẹ a mọlẹ; ṣugbọn bi oju rẹ ba buru, ara rẹ pẹlu a kun fun òkunkun.

Luk 11

Luk 11:24-35