Luk 11:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, bi o ti nsọ nkan wọnyi, obinrin kan nahùn ninu ijọ, o si wi fun u pe, Ibukun ni fun inu ti o bí ọ, ati ọmú ti iwọ mu.

Luk 11

Luk 11:20-32