Luk 11:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi Satani si yàpa si ara rẹ̀, ijọba rẹ̀ yio ha ṣe duro? nitori ẹnyin wipe, Nipa Beelsebubu li emi fi nle awọn ẹmi èṣu jade.

Luk 11

Luk 11:9-28