Luk 1:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi iṣe awọn alufa, ipa tirẹ̀ ni ati ma fi turari jóna, nigbati o ba wọ̀ inu tẹmpili Oluwa lọ.

Luk 1

Luk 1:3-12