Luk 1:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn mejeji si ṣe olododo niwaju Ọlọrun, nwọn nrìn ni gbogbo ofin on ìlana Oluwa li ailẹgan.

Luk 1

Luk 1:1-11