Luk 1:42 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ke li ohùn rara, o si wipe, Alabukun-fun ni iwọ ninu awọn obinrin, alabukun-fun si ni fun ọmọ inu rẹ.

Luk 1

Luk 1:36-43