Luk 1:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angẹli na si tọ̀ ọ wá, o ni, Alãfia iwọ ẹniti a kọjusi ṣe li ore, Oluwa pẹlu rẹ: alabukun-fun ni iwọ ninu awọn obinrin.

Luk 1

Luk 1:24-31