Lef 9:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun Aaroni pe, Mú ọmọ akọmalu kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ, ati àgbo kan alailabùku fun ẹbọ sisun, ki o fi wọn rubọ niwaju OLUWA.

Lef 9

Lef 9:1-6