Lef 7:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si fi gbogbo ọrá inu rẹ̀ rubọ; ìru rẹ̀ ti o lọrá, ati ọrá ti o bò ifun lori,

Lef 7

Lef 7:1-6