Lef 5:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si mú wọn tọ̀ alufa wá, ẹniti yio tète rubọ eyiti iṣe ti ẹbọ ẹ̀ṣẹ, ti yio si mi i li ọrùn, ṣugbọn ki yio pín i meji:

Lef 5

Lef 5:2-10