Lef 26:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnyin o si jẹ ẹran-ara awọn ọmọ nyin ọkunrin, ati ẹran-ara awọn ọmọ nyin obinrin li ẹnyin o jẹ.

Lef 26

Lef 26:27-33