Lef 21:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati arabinrin rẹ̀ ti iṣe wundia, ti o wà lọdọ rẹ̀, ti kò ti ilí ọkọ, nitori rẹ̀ ni ki o di alaimọ́.

Lef 21

Lef 21:1-8