Lef 21:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sọ fun Aaroni pe, Ẹnikẹni ninu irú-ọmọ rẹ ni iran-iran wọn, ti o ní àbuku kan, ki o máṣe sunmọtosi lati rubọ àkara Ọlọrun rẹ̀.

Lef 21

Lef 21:10-24