Lef 18:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ máṣe bà ara nyin jẹ́ ninu gbogbo nkan wọnyi: nitoripe ninu gbogbo nkan wọnyi li awọn orilẹ-ède, ti mo lé jade niwaju nyin dibajẹ́:

Lef 18

Lef 18:15-30