Lef 15:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLUWA si sọ fun Mose ati fun Aaroni pe,

2. Sọ fun awọn ọmọ Israeli, ki o si wi fun wọn pe, Nigbati ẹnikan ba ní àrun isun lara rẹ̀, nitori isun rẹ̀ alaimọ́ li on.

Lef 15