Lef 14:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni ki alufa ki o paṣẹ pe, ki a mú ãye ẹiyẹ meji mimọ́ wá, fun ẹniti a o wẹ̀numọ́, pẹlu igi opepe, ati ododó, ati ewe-hissopu:

Lef 14

Lef 14:1-7