Lef 14:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o mú akọ ọdọ-agutan kan, ki o si fi i ru ẹbọ ẹbi, ati òṣuwọn logu oróro, ki o si fì wọn li ẹbọ fifì niwaju OLUWA:

Lef 14

Lef 14:4-16