Lef 14:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLUWA si sọ fun Mose pe,

2. Eyi ni yio ma ṣe ofin adẹ́tẹ li ọjọ́ ìwẹnumọ́ rẹ̀: ki a mú u tọ̀ alufa wá:

Lef 14