Lef 13:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o si wò o, si kiyesi i, bi iwú na ba funfun li awọ ara rẹ̀, ti o si sọ irun rẹ̀ di funfun, ti õju si mbẹ ninu iwú na,

Lef 13

Lef 13:8-18