Lef 1:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn alufa, awọn ọmọ Aaroni yio si tò ninu rẹ̀, ani ori ati ọrá wọn sori igi ti mbẹ lori iná, ti mbẹ lori pẹpẹ:

Lef 1

Lef 1:6-12