Lef 1:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa na ki o si mú u wá si pẹpẹ na, ki o si mi i li ọrùn, ki o si sun u lori pẹpẹ na; ẹ̀jẹ rẹ̀ ni ki o si ro si ẹba pẹpẹ na.

Lef 1

Lef 1:7-17