Lef 1:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ọrẹ-ẹbọ rẹ̀ ba si ṣe ti agbo-ẹran, eyinì ni ti agutan, tabi ti ewurẹ, fun ẹbọ sisun; akọ ni ki o múwa alailabùku.

Lef 1

Lef 1:1-17