Kol 4:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori mo jẹri rẹ̀ pe, o ni itara pupọ fun nyin, ati fun awọn ti o wà ni Laodikea, ati awọn ti o wà ni Hierapoli.

Kol 4

Kol 4:6-18